Èyí ni àw¿n EWÌ À¿EY¿RÍ ÒMÌNIRA NÀÍJÍRÍÀ tí mo kó j¿ pap¿¿: Ó j¿¿ ohùn ìdùnnú fún mí púp¿¿ láti k¿ ìwé àkój¿p¿¿ ewì yìí. A k¿ ìwé ewì yìí ni àsìkò tí oríl¿¿-èdè Nàíjíríà pé ¿g¿¿ta ¿dún láti ¿e àyàjó¿ ¿j¿¿ ìbí r¿¿ náà; ti wón ¿e À¿EY¿RÍ ÒMÌNIRA ¿G¿TA ¿DÚN ORÍL¿¿ ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ náà. Àw¿n ewì j¿ ohun àbálàye tí ó j¿ ¿m¿ Yorùbá lógún. Ní ayé àtij¿¿ ní ilè Yorùbá, ò un ni àw¿n bàbá-¿lá wa máa ¿ lò fún ìmò¿, ìmò¿ràn àti ¿¿k¿¿, ¿ùgbó¿n won kìí k¿¿¿ síl¿¿ nítorí pé, w¿n kò ní ìmò¿ mò¿ó¿k¿¿mò¿ó¿kà rárá. Orísírísí ewì ni ó wa, orísírísí ¿¿nà ni a sì lè pín ewì sí. Èrò ¿kàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkój¿p¿¿ ewì yìí. Nàìjíríà (/nä¿d¿¿r¿¿/) j¿¿ Oríl¿¿-èdè Olómìnira. Ìj¿ba Àpap¿¿ il¿¿ Nàìjíríà j¿¿ oríl¿¿-èdè tí ó ní ìj¿ba ìpínl¿¿ m¿¿rindínlógójì tó fi m¿¿ Agb¿¿gb¿¿ Olúìlú Ìj¿ba Àpap¿¿. Oríl¿¿-èdè Nàìjíríà wà ní apá Iw¿¿ Oòrùn il¿¿ Áfríkà. Oríl¿¿-èdè yí pààlà p¿¿lú oríl¿¿-èdè Benin ní apá ìw¿¿ Oòrùn, ó tún pààlà p¿¿lú oríl¿¿-èdè olómìnira ti Nij¿r ní apá àríwá, Chad àti Kam¿róòn ní apá ìlà Oòrùn àti Òkun Atlantiki ni apá gúúsù. Abuja ni ó j¿¿ Olú-Ìlú fún oríl¿¿-èdè náà. Bí ó til¿¿ j¿¿ pé Nàìjíríà ní ¿¿yà púp¿¿, àw¿n ¿¿yà m¿¿ta ni w¿¿n tóbi jùl¿. Àw¿n w¿¿nyí ni ¿¿yà Yorùbá, ¿¿ya Ìgbò ati ¿¿yà Hausa.