Ó j ohùn ìdùnnú fún mí púp láti k ìwé àkój p ewì yìí. A k ìwé ewì yìí ni àsìkò tí oríl -èdè Nàíjíríà pé g ta dún láti e àyàjó j ìbí r náà; ti wón e ÀSEY RÍ ÒMÌNIRA G TA DÚN ORÍL ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ. Àw n ewì j ohun àbálàye tí ó j m Yorùbá lógún. Ní ayé àtij ní ilè Yorùbá, ò un ni àw n bàbá-nlá wa máa n lò fún ìmò , ìmò ràn àti k , sùgbó n won kìí k síl nítorí pé, w n kò ní ìmò mò ó k -mò ó kà rárá. Orísírísí ewì ni ó wa, orísírísí nà ni a sì lè pín ewì sí. Èrò kàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkój p ewì yìí. "S r Sókè!" ni àk lé Ìwé Ìsípayá Ewi Yorùbá yìí (Speak Up!). Àk lé ìwé yìí j jáde nínú r àw n d Nàíjíríà (A popular phrase that has informally become the name of the millennial slang of generations in Nigeria). Àw n d se ìw de #EndSARS ní Oríl -èdè Nàíjíríà: ní ìpínlè Èkó, Ekiti, y , Ondo, Osun, Kwara ati Abuja lati bá àw n olórí àti àw n m ilu s r ní dún 2020. Kí ni ìtum "S r Sókè" àti Ìw de tí àw n d n se àgbékal r yìí? Wó n fi Ìw de #EndSARS yìí s pé kí àw n l pa má se pa àw n ará ìlú m , pàtàkì jù l àw n d àti pé kí olúkúlùkù s àw n è dùn kàn w n gbogbo jáde ni oríl -èdè NÀÍJÍRÍÀ.