Nínú ¿dún 2019, ¿m¿kùnrin r¿`, àbísìkejì, tí ó fìgbà kan j¿¿ ¿m¿ ogun ojú omi il¿` Am¿¿ríkà náà tún pa ara r¿`. L¿¿yìn èyí ni Adé¿lá tún rí àw¿n ¿`r¿` kòbákùngbé tí ¿k¿ r¿` k¿ nípa r¿` sí orí ¿`r¿ ayélujára kà dé ibi pé òun lòun fa ikú ¿m¿ àw¿n ¿`hún.
Ìrora, ìf¿¿, àti ìgbàgb¿¿ Adé¿lá fara hàn kedere nínú ìtàn àgb¿¿gbárímú yìí tí ó gbé kal¿` ní ìrètí pé yóò dé etígb¿`¿¿ àw¿n tí yóò wúlò fún.
"Nínú ìwé yìí, Adé¿lá gbé ìtàn akíkanjú obìnrin kan tí ó dojú k¿ wàhálà ab¿¿le kal¿`. L¿¿yìn-ò-r¿yìn, p¿`lú ìrànl¿¿w¿¿ ¿ló¿run, ó jáwé olúborí." Iloh, Friday Okechukwu (Ph. D)
Dieser Download kann aus rechtlichen Gründen nur mit Rechnungsadresse in A, D ausgeliefert werden.