2,99 €
2,99 €
inkl. MwSt.
Sofort per Download lieferbar
payback
0 °P sammeln
2,99 €
2,99 €
inkl. MwSt.
Sofort per Download lieferbar

Alle Infos zum eBook verschenken
payback
0 °P sammeln
Als Download kaufen
2,99 €
inkl. MwSt.
Sofort per Download lieferbar
payback
0 °P sammeln
Jetzt verschenken
2,99 €
inkl. MwSt.
Sofort per Download lieferbar

Alle Infos zum eBook verschenken
payback
0 °P sammeln
  • Format: ePub

Àkọ́lé ẹ̀kọ́ yìí gan an ni "lati di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí." Ó ní ìpìlẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ yìí. Ní èdè mìíràn, ìwé yìí fi nyé wa gedegbe ohun tí àtúnbí jẹ́ ati bí a ti lè di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí ní ìbámu pẹlu Bibeli. Omi túmọ̀sí ìrìbọmi nínú odò Jọrdani Bibeli sì wipe gbogbo ẹ̀?ẹ̀ wa pátá ni ó ti rékọjá sórí Jesu nigbati Ó ?e ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi. Johannu ni a?ojú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí Ó sì tún jẹ̀ àrọ́mọdọ́mọ Aaroni Olórí alufa. Aaroni gbé ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lé orí ewúrẹ́ alààyè náà ó sì kó gbogbo ẹ̀?ẹ̀ Israẹli ti ọdọdún sórí rẹ̀ ní ọjọ́ ètùtù. Èyí jẹ́ òjìjí ohun rere tí…mehr

  • Geräte: eReader
  • mit Kopierschutz
  • eBook Hilfe
  • Größe: 5.5MB
  • FamilySharing(5)
Produktbeschreibung
Àkọ́lé ẹ̀kọ́ yìí gan an ni "lati di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí." Ó ní ìpìlẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ yìí. Ní èdè mìíràn, ìwé yìí fi nyé wa gedegbe ohun tí àtúnbí jẹ́ ati bí a ti lè di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí ní ìbámu pẹlu Bibeli. Omi túmọ̀sí ìrìbọmi nínú odò Jọrdani Bibeli sì wipe gbogbo ẹ̀?ẹ̀ wa pátá ni ó ti rékọjá sórí Jesu nigbati Ó ?e ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi. Johannu ni a?ojú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí Ó sì tún jẹ̀ àrọ́mọdọ́mọ Aaroni Olórí alufa. Aaroni gbé ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lé orí ewúrẹ́ alààyè náà ó sì kó gbogbo ẹ̀?ẹ̀ Israẹli ti ọdọdún sórí rẹ̀ ní ọjọ́ ètùtù. Èyí jẹ́ òjìjí ohun rere tí mbọ̀ wá. Ìrìbọmi Jesu ni àpẹẹrẹ ètò ìgbọ́wọ́lé. Jesu ?e ìrìbọmi ní ìlànà ètò ìgbọ́wọ́lé lórí nínú odò Jọrdani. Nitoridi èyí Ó kó gbogbo ẹ̀?ẹ̀ aiyé yìí lọ nípasẹ̀ ìrìbọmi Rẹ̀. Ó sì kú lórí àgbélèbú lati san gbèsè ẹ̀?ẹ̀. ?ugbọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ Kristiẹni ni kò mọ ìdí tí Jesu fi ?e ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi nínú odò Jọrdani. Ìrìbọmi Jesu ni kókó ọ̀rọ̀ ìwé yìí, ati apákan tí ó jẹ́ dandan sí ìhìnrere ti omi ati ti Ẹ̀mí. A lè di àtúnbí bí a bá nígbàgbọ́ sí ìrìbọmi ti Jesu ati ti ikú Rẹ̀ lórí igi àgbélèbú.


Dieser Download kann aus rechtlichen Gründen nur mit Rechnungsadresse in A, B, CY, CZ, D, DK, EW, E, FIN, F, GR, H, IRL, I, LT, L, LR, M, NL, PL, P, R, S, SLO, SK ausgeliefert werden.